NITORI TINUBU: AWỌN OLOṢELU FẸẸ DA WAHALA NLA SILẸ NILẸ HAUSA

Ойын-сауық

We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Пікірлер: 28

  • @adebayoolayemi4865
    @adebayoolayemi486512 күн бұрын

    Asa buruku ni l'ooto, sugbon t'o ba je wipe ohun ti o le mu nigeria pin niyen, ki tinubu tete f'owo si.Ti a ba pin tan Olorun a fi ona abayo koro n'ibe han wa.

  • @RazeedAyinki
    @RazeedAyinki13 күн бұрын

    Olorun osaun wa Amin

  • @LukmanAgbaje
    @LukmanAgbaje13 күн бұрын

    Hmmmmm Nigeria

  • @timothywale8055
    @timothywale805513 күн бұрын

    Hmmm, kangun, kangun, kangun, oma kangun sibikan saa ni, Yoruba Nation ni ona abayo si gbogbo rogbodiyan yii , ki wahala le dopin

  • @user-vg8nm3wt9d
    @user-vg8nm3wt9d13 күн бұрын

    Walahi oloselu nigeria yoo pa nigeria run

  • @biochar.
    @biochar.12 күн бұрын

    Na Bobrisky cause am sir

  • @alababalogun3362
    @alababalogun33628 күн бұрын

    YORUBA NATION 1

  • @bigbirdrewire
    @bigbirdrewire13 күн бұрын

    Koni dafun gbogbo won Nile ahusa

  • @LukmanBakare-iv2tm
    @LukmanBakare-iv2tm13 күн бұрын

    Igbawo ni rogbodiyan oni sele won kan nfi pamo ni ki kaluku mura sile

  • @giveway...6838
    @giveway...683813 күн бұрын

    Were ni okunrin yii jare! Awon Oloselu yii sha....

  • @AyotundeOjuade
    @AyotundeOjuade12 күн бұрын

    Idagbasoke ni Nigeria abi kileunwi, nobody thinks of stable electricity, no electricity no development, no electricity no security, no electricity no job advantages, refinery is there without renovation, just dey play, awon ika eda gbogbo.😢😢😢😢😢

  • @odunolaalli6773
    @odunolaalli677313 күн бұрын

    Ki ijoba ya gbe okunrin Yi lati wa so tenu re.

  • @MrTjogunsola
    @MrTjogunsola13 күн бұрын

    Awon ika eniyan eje kiwon danwo Naija tan niyen.

  • @SoulyaAtanda
    @SoulyaAtanda13 күн бұрын

    Iru radarada wo ni eleyi tan so

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp13 күн бұрын

    OMG OOO

  • @Omowunmi0412
    @Omowunmi041213 күн бұрын

    Ki I se Awon Hausa awon Fulani ni won nse gbogbo nkzn yi ..Sugbon SAMOA yen ko to si Nigeria rara .Asise nla ni eleyi ma je ti Tinubu ba fowo si .Awon ile Hausa o ni gba eleyi o .A tete ya kiakia lati pin Nigeria is were ni

  • @mariamasie9329
    @mariamasie932913 күн бұрын

    Ohun ti oju won wa ni oju won ri ni Nigeria, ki Olorun wa pelu Omoyele Sowore to fi ojojumo wa leyin Mekunnu.

  • @adebayoolayemi4865

    @adebayoolayemi4865

    12 күн бұрын

    Oro rirun l'o n so.

  • @mariamasie9329

    @mariamasie9329

    12 күн бұрын

    @@adebayoolayemi4865 kilo ri,eyin lo kan, mo kan lewo

  • @AzeezJeleelOlanrewaju
    @AzeezJeleelOlanrewaju7 күн бұрын

    Igbos and lie are and one and two

  • @imoleadini
    @imoleadini12 күн бұрын

    Edakun.sewonfi kan.baba wereyi.wipe komo.yawoka kilonfowo nase eyin.baba oloribu.akosi.bero baba.onigbese onigbese.gbogbo gbani.wonwa owoyiya.ka.awon.onise.minju owoyiyalo baba Tinubu.eyeyawokamo wonfowo yiya.seyinni eyin.jereni afowo yiyasa.ojigan niyin.ninu owo.yiya.sele san gbese tejeyi.keto kuro.nipo.eyin babaosi.akotiletayi.efakun.ewabi.bosilo.ojare owoyiya.sasani.enigbo.royinpe wonkowo.wole afikemo.yawo nigbogbogba.bopolo yin Obamo ntiose mo baba.ewabi gbalo.ojare baba.onigbese.niyin

  • @BossaFola
    @BossaFola9 күн бұрын

    Ejo ki la tan ra fun? Ai mon oye omo Igbo in diaspora same gender fe ara won

  • @adeyemiyusuff6458
    @adeyemiyusuff645813 күн бұрын

    Ki ALLAH ma sowa

  • @LukmanBakare-iv2tm
    @LukmanBakare-iv2tm13 күн бұрын

    Tinubu kounse Muslim gidi koun kirun tele igba to fi agidi je aare loso arae di Muslim oju aye

  • @adebayoolayemi4865

    @adebayoolayemi4865

    12 күн бұрын

    O san igba l'enu e buruku ti o fi n so isokuso yen.

  • @Jimoh.Gaskia
    @Jimoh.Gaskia13 күн бұрын

    Kiwon.odale.oro.tiowanileyi.enihawifun.oba.Olorun..jekiogbo.tiebagbagbe.Baba.Akintoye.wiwipe.kapin.awon.ojelu.yi.nitori.imotiarawon.nikan.awon.gomina.ile.yoruba.yi.tigbagbepe.oro.masunkikiku.ita.yiose.nipa.onikaluku.ounti.onikalukubase.oro.itani.leyin.waola

Келесі