ẸYIN GOMINA ILẸ YORUBA, Ẹ TETE DIDE LORI ỌRỌ AWỌN FULANI DARANDARAN YII O

Ойын-сауық

We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Пікірлер: 31

  • @oduatide6849
    @oduatide684919 күн бұрын

    Yoruba Nation is the only solution

  • @juliustomike1986
    @juliustomike198620 күн бұрын

    Yoruba national la fe

  • @adeyemiyusuff6458
    @adeyemiyusuff645819 күн бұрын

    Mama Alaroye you are too much

  • @user-hd7yd6py8i
    @user-hd7yd6py8i19 күн бұрын

    Fulani cow eating crops in yoruba land is a plan work program.

  • @user-hp5um9hs1b
    @user-hp5um9hs1b19 күн бұрын

    President Nigeria eru fulani ni won ati awon government's there not have any power to do anything for fulani herdsmen control everywhere in Nigeria will don't have Good president

  • @mustaphaodeshina5111
    @mustaphaodeshina511119 күн бұрын

    Good job by Alaroye

  • @mariamasie9329
    @mariamasie932919 күн бұрын

    Apariwo pe ki won ma dibo fun APC pe ki won dibo fun Omoyele Sowore, emura si ema dibo fun awon Oloselu Ole akotileta arungun odaju.

  • @Me19011

    @Me19011

    16 күн бұрын

    Kini Sowore le Se E ye tan ara yin sir.

  • @adesinawasiu7993
    @adesinawasiu799319 күн бұрын

    Yoruba nation is the only way out and solution

  • @papingodee7523
    @papingodee752319 күн бұрын

    Hummmnn

  • @michaelobikanye1997
    @michaelobikanye199719 күн бұрын

    Ogbomije loju eni isele ilu ondo, Amotekun ati fulani ni ipinle Ondo.Bi aba munra si aibikita yi,fulani oni pe lewa kuro lori ile baba wa.Agbodo fi eleyi to aare orile ede leti lai ja fara.Amotekun gbodo ma gbe ibon to lagbara tabi ka tu nwon ka.Kaye fi nwon sinu ewu.

  • @adekunlefodilullahmfa7700
    @adekunlefodilullahmfa770019 күн бұрын

    Were nii awon tii wan pe ara wan ni Amontekun .awon oni yeye ooo

  • @lanrea9373
    @lanrea937319 күн бұрын

    Gbogbo owo ti won npin nwon ko si apo won ni.

  • @OlowoleSunday-xg1gv
    @OlowoleSunday-xg1gv19 күн бұрын

    Eyi buru jọjọ

  • @TejuAdejuwon
    @TejuAdejuwon18 күн бұрын

    Yoruba Nation lafe ni kiakia

  • @ajegunmowasiu3948
    @ajegunmowasiu394819 күн бұрын

    Yoruba nation lafe

  • @kyrieeleison7065
    @kyrieeleison706519 күн бұрын

    Nigeria insecurity is political.

  • @kehindebellosikirubello989
    @kehindebellosikirubello98919 күн бұрын

    Amotekun tabi amotadie amotekun to nla plate amotekun to ngba ruin obirin Wole amotekun to npin eyinje amotekun ipo niwon nle pelu owo

  • @ruthlawal4260
    @ruthlawal426018 күн бұрын

    Ko didadan ki won lo ibon lati fi ja, Ki wo lo ohun ija tiwa tiwa lati fi ja. Ki won bu ifoju lu won ki gbogbo won wogbo lo, Mi orope awon Amoteku ni gbara rara, abi kini agbara teni Ti e le lo lati koju ija sawon oloriburu fulani ti won fi seyi lese bayan oma se oo, kosi agbara mo, enu lasan ni won ni.

  • @lukmonolamilekan8616
    @lukmonolamilekan861619 күн бұрын

    Ooku sowo awon gomina ile yooba to ba jee wipe akeredolu mbee laye iru katikati yio le sele ni ondo

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo668119 күн бұрын

    IYA ALAROYE E KU OHUN SE GBOGBO ORO TI SUNDAY IGBOHO SO WA SE BAYI ABI KO SE EYI MA WA LAGBARA GAN NI O A SI SO PE ONE NIGERIA NI WA SUGBON EYA KAN LEVSE NKAN TI EYA MIRAN KO LE DAN WO E JEKI A LO LOTTO KI OLORUN SE INA WA NIRE A JUSE FUN WA NILE YORUBA LAGBARA OLORUN ASE

  • @adeniyimabosanyinje7597
    @adeniyimabosanyinje759719 күн бұрын

    Awon gomina wa ko le ri nkankan se si. Nitoripe awon gomina wa na ni ninu awon malu ti awon Fulani daran daran main Dey play

  • @samsonolayiwole6398
    @samsonolayiwole639819 күн бұрын

    All this governors people dey listen to News at all hissss.....

  • @adeyemoademolajammy2002
    @adeyemoademolajammy200219 күн бұрын

    Idirin ni awon amotekun, nigba ti awon fulani n sa won lada ti amotekun n yinbo won soke ki fulani lee salo.

  • @roselinebolanle9404
    @roselinebolanle940419 күн бұрын

    Yoruba wa ngbele won forunro talase?🤔

  • @lanrea9373
    @lanrea937319 күн бұрын

    Kilo de ti Tinubu ko le fun won ni oun ija. Papa oye ki awon gomina yi ti kuro lori oye nigbati ati ni Democratic Republic of Yoruba. Ki won kuro ki awon Adele wa gba ise lowo won.

  • @adebolagbadamosi3745
    @adebolagbadamosi374518 күн бұрын

    Stop buying beef.

  • @OlowoleSunday-xg1gv
    @OlowoleSunday-xg1gv19 күн бұрын

    Orilẹ ede yoruba lafe

  • @Jimoh.Gaskia
    @Jimoh.Gaskia19 күн бұрын

    Awon.gomina.wo.awon.tiwoni.hagbodo.kuro.loko.eru.awon.fulani.hausa.yi.lewani.kiwon.osoro.orowoni.wonoso.awon.onijekuje.awon.ole.onijibiti

Келесі