MORNING PROPHETIC PRAYER

MORNING PROPHETIC PRAYER

Пікірлер: 14

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Amin amin amin amin Jeeesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    No more war in my life, Jesus is coming soon

  • @atinukealese2386
    @atinukealese238614 күн бұрын

    Halleluyah, praise the Lord.

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Amin fireeee

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    NI oruko Jeeesu, gbogbo ami ofo ninu aye mi ati awon omo mi ba ina jade, agbara ati ami ofo ninu aye mi ati awon omo mi ba ina jade loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Halleluyaaa, halleluyaa, halleluyaa, halleluyaa, halleluyaa, halleluyaa, halleluyaaaaaa

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Oluwa ba mi rin, iwo ni o mo ona ju mi lo, ba awon omo mi rin irinajo aye won, nitori Iwo nikan lo mo ona yi ju gbogbo aye lo, Iwo lo mo ibi to da mo won, Iwo lo ile aanu ati ogo won, Oluwa jare ba awon omo mi rin ki irin won yori ri rere ati iyanu loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Olorun Caleb Olulade ooo, gbogbo oju to n so emi ati awon omo mi kiri to n le alaanu ati oluranlowo lara wa, oju naa fo loruko Jesu, Oluwa bu ifoju lu oju naa ati oloju loni loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Awon oju to n monitor ogo mi ati awon omo mi, Oluwa bu ifoju lu won, oju ati oloju to n monitor aye emi ati awon omo mi, Oluwa wo won danu, Oluwa fo won danu loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Gbogbo emi iyagan lara mi ati awon omo mi, ile gbe won mi loni loruko Jesu, emi iyagan ohun rere gbogbo, iyagan owo, alaafia, iserere, aanu ati iyanu loni ile gbe won mi ninu aye emi ati awon omo mi loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Ni oruko Jeeesu, Emi mimo ooo, Ayeraye gbe mi de ibi ti ogo mi ti maa soro, ibi ti ogo awon omo mi maa ti fohun, Oluwa gbe won de be, nibi ti iyanu ti maa sele ninu aye wa, ninu ile itura ati ogo wa, Ayeraye gbe wa debe, mu wa de ibe

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Ni oruko Jeeesu, ami ofo ninu ago ara ile Raphael ati Emmanuel ba ina jade, gbogbo ami ofo lara awon omo bibi inu mi, ati ninu aye mi gangan ni oruko Jesu ba ina jade pelu owo agbara

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Olorun Olulade mase da mi da isoro mi, je ki aanu jade simi nigba ti n ko lero, aanu lojiji, oore ofe ojiji, iyannu ojiji, jade simi, jade si awon omo mi ni ibi ti ona ti di, nibi ti ko sona, aanu Juda, yo si mi tomotomo loruko Jesu

  • @adeyemiileaje4238
    @adeyemiileaje423815 күн бұрын

    Olorun AK-47, ninu ose ti mo wa yi, je ki ona awon omo mi ni ojutu, wa ojutu si oro Raphael, ba mi wa ona abayo si isoro to n koju awon omo mi, (Raphael), dari alaanu ati oloore ti kii su, ti kii re sinu aye awon omo mi, Oluwa ba mi mu won mo ona otito ati ona iye pelu iselogo loruko Jesu