AMAZING OLDIES MINISTRATION - MO RO NU TITI ASE ASAN LAYE JE & OPO LA PE DIE LA YAN

Amazing oldies gospel songs that preaches about the kingdom of God, calling people to repentance and ignore the vanity of the world...
LYRICS :-
MO RO NU TI ASE ASAN LAYE JE 1:39
Mo ronu titi, a se asan ma laye je /2ce
Mo ronu jinle a se ofo laye o
Imule m'ofo laye o
Asan! Asan ma laye je
Eniyan d'ori re kodo ko ronu wo
Bi a ti s'ohun gbogbo b'ohun ikehin
Tori ojo o duro d'enikan
Asiko ku fe fe
Bi o j'olowo o, wa ku
Bi o j'oloro o, wa lo
Bo se talaka, wa koja lo s'orun
Asan! Asan ma laye je.
Bi o j'ologbon, wa ku
Bo lewa pupo, wa lo
Bo j'oburewa, wa koja lo s'orun
Asan Asan ma laye je
Repeat --- Eniyan d'ori kodo ko ronu wo
Call - sora o omo eniyan e sora pupo
Rep - sora o omo igbala e sora pupo
Ile o /4x
Ile aye o oja ma lo je oo
OPO LA PE, DIE LA YAN 6:25
Opo la pe, die la yan
Ninu die na
Baba ka mi mo won
Voc 1
Ibeere ko loni ise o
Ase dopin loni ise
Gb'oju soke ko wo Jesu
T'ewo adura, ka wa le sin dopin
Repeat chorus
Voc 2
Sodomu ko ati Gomora
Okiki won o yi aye ka
Sugbon won se, a pa won run
Loti, si ye pelu awon to yee
Repeat chorus
VOC 3
Aye nbi si, aye nresi
Won ko eyin s'Oluwa
A si fi omi pa aye run
Noah lo ye pelu awon to yee
Repeat Chorus
VOC 4
A fi Jesu f'awon Ju
Pelu olosha meji
Won kan won mo agbelebu
Okan ri 'ye ninu Jesu Kristi
Repeat Chorus
VOCAL 5
Jesu wipe ki se gbogbo
Awon to npe mi l'Oluwa
Ni yio ya 'yo, ni yio segun
Ni yio gba ade iye nikeyin.
Repeat chorus..... Opo la pe etc.

Пікірлер