TINUBU, BẸẸ ṢE FẸẸ ṢE E YII GAN-AN LO DAA O

Ойын-сауық

We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Пікірлер: 28

  • @wosilatamosu9017
    @wosilatamosu90176 күн бұрын

    Awon Omo OLÉ Omôjaguda IKA ni Won Ijoba ILU gangan koni OFI toduro Dédé ARE TINUBU FÉLICITATIONS Ijeya ni oyewon

  • @bose1462
    @bose14626 күн бұрын

    They are so plenty

  • @deedotist

    @deedotist

    6 күн бұрын

    Plenty? Do you know anyone that is doing such act?

  • @odunolaalli6773

    @odunolaalli6773

    5 күн бұрын

    Very plenty.

  • @giveway...6838
    @giveway...68385 күн бұрын

    Awon oga lbise naa mo si jare! Oga ilese ati eni to gba owo ye ewon gbere lo ye kiwon fun gbogbo won pata!

  • @abdulkarimsalman
    @abdulkarimsalman6 күн бұрын

    ❤ Alaroye apejuwe te muwa yi dara pupo ❤ko ni reyin lase edumare ❤

  • @sakenatafolabi8666

    @sakenatafolabi8666

    5 күн бұрын

    Amin 🙏

  • @giveway...6838
    @giveway...68385 күн бұрын

    👍 Beeni o

  • @Adugbo
    @Adugbo5 күн бұрын

    Kini oruko gbogbo won. Iku ni ere ese

  • @LukmanBakare-iv2tm
    @LukmanBakare-iv2tm6 күн бұрын

    Ejo eye fiete sile kiema pa lapalapa awon tio joko sile ijoba ti wonko bilionu nko eri so si iyen ti won fi opolopo milionu ra taya moto ejo ejeka jawo lapon tioyo omo yoruba

  • @temiadeloye8800
    @temiadeloye88006 күн бұрын

    Thanks for exposing this. Possibly it would make those people involved in this reflect and cease from this shameful act. May Almighty God give us conscience not to sell our soul for money. May God not let ongoing agonising poverty or greed spoil our good names and heaven. Amen. Thanks Ma. God bless you.

  • @AyotundeOjuade
    @AyotundeOjuade5 күн бұрын

    Se ti Omo Nigeria bajede kuro nile, se kosi asobode lonu boundaries wa ni, abi kosi customs, se ilu tikosi data base tabi akosile kankan fun eniyan letifese iru inkan yen, abi awon ara ilu oyinbo tiwon campaign fun are ni kiwonmu, abi ilu ti kosina electricity ni etife ni proper investigation, gbogbo wa lamo ountoye fun Nigeria sugbon otito Oro Koro, (truth is always bitter) labe one Nigeria hmmmmmm kosi hmmmmmmmm.

  • @Oodua-ii
    @Oodua-ii5 күн бұрын

    Please learn to 👍good content. Oso ju mi koro is a good content producer. 💡

  • @haynehifanny8006
    @haynehifanny80066 күн бұрын

    Tani ẹbi wa l'ọwọ bikòṣe awọn alatilẹyin wọn níbi? Oṣeeṣe kojẹ wípé Apa-pin ni wọn nfi owo nà ṣé.

  • @odunolaalli6773

    @odunolaalli6773

    5 күн бұрын

    Yes u are right. Apapin ni. Some pple have shared in it.

  • @Patoskyfanpage
    @Patoskyfanpage6 күн бұрын

    How is it possible that someone that has resigned from work and relocate to another country, continue collecting salary from the work he resign already, is not possible, and that is the corruption we still talking about. Nigeria is a fail country

  • @odunolaalli6773

    @odunolaalli6773

    5 күн бұрын

    Is very real. Pple in charge salary are collecting part of it. Level of corruption in Nigeria is very high.

  • @adexpart8933
    @adexpart89335 күн бұрын

    True talk

  • @jamesolami-ti4jg
    @jamesolami-ti4jgСағат бұрын

    Runny

  • @beatricejegede530
    @beatricejegede5305 күн бұрын

    Enh, awon ati awon oga won ni won jo dipo. Eleyi wopo laarin awon onise ijoba paapa awon uniform men. We are just too curupt and can't imagine it. Sych people should be deported and imprisoned

  • @user-yv1ze4tm6e
    @user-yv1ze4tm6e6 күн бұрын

    Efiya je ori gbogbo won

  • @kehindeadenusi7493
    @kehindeadenusi74936 күн бұрын

    Ẹjọ tani wa ni yẹ o, nigba ti ẹni abo tonu moju awọn ton wọle ati toun jade ati pe ko si ikọ tonu moju to awọn oṣiṣẹ lati mọ awọn ti ku ati awọn to wa laaye. That's the fault of the government's as a hole. So they should keep quiet and do their jobs properly, they says there's no jobs and that's another department just created and should be on trust and reporting to someone in charge and there should be on routine.

  • @kemoblunsky3794
    @kemoblunsky37946 күн бұрын

    Ki wa ni ijiya gbogbo awon ojelu Nigeria ti won pe ara won ni oloselu?.... ko yo anybody ninu oselu sile, let us start to rearrange the whole scenarios from the TOP.

  • @LukmanBakare-iv2tm
    @LukmanBakare-iv2tm6 күн бұрын

    Owo aare gan komo igba ti ja eko lole titi sebi oti gbe ole si abuja awa yoruba aferan ki ama pon jebe lakisa

  • @user-ie8zf1he4t
    @user-ie8zf1he4t6 күн бұрын

    Oloriburku ni yin alaroye. Enigbe Adiye. Loja enikiwonyegi fun. Enitogbe. Odidi malu. Kiniesefun. Konidafunyin. Efete sile enpa lapalapa. Awon oniranu. Won fe magbe awon Omo. Nigeria mora

  • @abigailjohnson1698

    @abigailjohnson1698

    5 күн бұрын

    Iwo gan lobayeje.oti Han gbangba pe owa Lara awon ton huwa Ibaje yi.

  • @user-hp5um9hs1b
    @user-hp5um9hs1b6 күн бұрын

    E yin o mo pe lati oke lo ti wa ko se ati isale e mo pe president nigeria na ko san tax to je pe president na san tax gbogbo awon government ole ni gbogbo won lati oke de isale ole ni gbogbo won ati president ati awon Oleselu Ojelu ni gbogbo won ati president awon government there all robbery and craze

Келесі