Oriki Orile Aresa - Eulogy | Yoruba Oral Literature

Yetunde Elewi eulogized the descendants of the ancient Arẹ̀sà lineage and gave advice for people to take their future serious by acquiring values that would benefit their life in future because the future starts now!
Nínú ewì yìí, Yetunde Elewi ki oríkì orílẹ̀ arẹ̀sà ní ṣókí àti ọ̀rọ̀ ìyànjú lórí ọjọ́ iwájú fún gbogbo ẹni tó bá fé gbé ilé ayé ṣe ohun rere.
Àṣìṣe kọ́ ni bí a bá sọ pé Oríkì Orílẹ̀, Oríkì Ìdílé, Oríkì Ìlú àti Oríkì Àwọn Ènìyàn jẹ́ òpómúlérò fún àwọn ewì atẹnudẹ́nu nílẹ̀ Yorùbá. Kódà, bọ́yá ni ẹni tí kò bá mọ oríkì dé àyè ibi tó lápẹrẹ ṣe le rọ́wọ́ mú láwùjọ nínú ewì kíké.
Oríkì máa ń jẹyọ gbáà nínú ewì. Fún ìdí èyí, pọndandan ni fún akéwì láti mọ oríkì.
Fully subtitled in English
AIF MEDIA is a medium (of AIF YORÙBÁ CULTURAL CENTRE)with passion to unite Yorùbá people to their heritage; promote and preserve godly virtues from Yorùbá culture, tradition and lifestyle; and give poetic admonitions.
Our networks:
YÒRÙBÁDÙNLÉDÈ | ÌTUMỌ̀ | BIBLICOPOETRY
Enjoy our educational videos!
To learn more about us, please visit our website: aifacademy.org
For enquiries, send your request to support@aifacademy.org
Facebook: AIF MEDIA
bit.ly/AIFMEDIA-Facebook
Instagram: AIF MEDIA
bit.ly/AIFMEDIA-Instagram
Twitter: AIF MEDIA
bit.ly/AIFMEDIA-Twitter
Watch, subscribe and share with others.
#lítírésọ̀ #literature #akewi #oroiyanju #language #aifmedia #yorùbá #media #yoruba #culture #ewi #origin #history #name #nigeria #tribe #worldlanguage
Recorded on September 27, 2020

Пікірлер: 2

  • @aifmedia
    @aifmedia2 жыл бұрын

    Our dear subscribers! For your views and kind comments, a dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ yín. We are aware of your love and support. But there are countless others who need what we do and offer. We don't know them but you do! Be more part of this movement to unite Yorùbá people to their godly heritage and values. Recommend us, tell someone about us, share us and follow us on our social platforms @aifmedia to get closer. Á jú ṣe o!

  • @funkeosisami6652
    @funkeosisami66522 ай бұрын

    Can I get a contact for an eulogy for a lost love one