ORÍKÌ OLÚKÒYÍ(Ìkòyí Ẹ̀sọ́ Ọmọ Agbọ̀n Iyún. Ọmọ A Kú Rangbọndan Níjọ́ T'ébi Ń P'ẹyẹ L'óko...

Пікірлер: 13

  • @wosilatamosu9017
    @wosilatamosu90173 жыл бұрын

    Awa niyen EMI IKOYI ESHO Omo Arogunyo IKOYI tii ko rii Ogun jaa to njaa Igboro Awikoko Akanda oro God.Blessed ojere omo Osijere Ara ré n'a ASEWA 👏❤️😇💯🙏💪

  • @lucyonikoyi6183
    @lucyonikoyi61833 жыл бұрын

    Thank you very much l love this ORi Mi wu

  • @olanrewajuogunde9021
    @olanrewajuogunde90213 жыл бұрын

    Wow....

  • @pelelegend4117
    @pelelegend41173 жыл бұрын

    Ori mi wu😉😉😉😘😻

  • @beatricepeters7393
    @beatricepeters73933 жыл бұрын

    Kaaasa Akanda. Eku ise akoni. Mo gbe osusu fun Akanda ooo. Kabo Akanda. Ko ni re Akanda ni agbara Olorun o Amin.

  • @fausateniola8488
    @fausateniola84882 жыл бұрын

    Thanks you sir

  • @daveteletech
    @daveteletech2 жыл бұрын

    Well done Sir. E ku ise rere

  • @fausateniola8488
    @fausateniola84882 жыл бұрын

    E se hun o,akanda awikonko ori mi wu o omi Ja bo loju mi . Emi ni omo aleri iku gan gun iwaju la ma fi gba ofa ni ile baba to bi mi lomo, God bless you sir

  • @rashidatbabalola2205
    @rashidatbabalola22053 жыл бұрын

    Cooool

  • @fausateniola8488
    @fausateniola84882 жыл бұрын

    🤣🤣

  • @richlyblessed3613
    @richlyblessed36133 жыл бұрын

    Their heads should swell in hearing this😁. Well done Akanda. God bless you real good.

  • @ftfethy4
    @ftfethy43 жыл бұрын

    Great job akanda oro you are the best all time god will continue protect you sir

  • @yinkaonikoyi5304
    @yinkaonikoyi53043 жыл бұрын

    Please I need the CD of ONIKOYI