OLOYE M.O. OGUNMOLA (OTUN OYO ATI OLUDASILE ILE EKO LADIGBOLU GRAMMAR SCHOOL, OYO)

Èyí jẹ́ iṣẹ́ àkànṣe pàtàkì lórí Ìtàn ìlú Ọ̀yọ́ àti àwọn ìlànà tí ó rọ̀ mọ́ yíyan Àláàfin, níbi tí a ti ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú Olóyè M.O. ÒGÚNMỌ́LÁ tí wọ́n jẹ́ Ọ̀tún Ọ̀yọ́ àti Olùdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ Ládìgbòlú Grammar School ní ìlú Ọ̀yọ́.
Ẹ má gbàgbé láti darapọ̀ mọ́ wa lójú òpó KZread (Subscribe) yìí láti máa gbádùn àwọn ohun Ìṣẹ̀dálẹ̀ wa gẹ́gẹ́ bí ọmọ Yorùbá àtàtà.

Пікірлер: 30

  • @americaneagleexpress9601
    @americaneagleexpress9601 Жыл бұрын

    We need fathers like this. Not thieves, pastors or area boys running the government. 100 years old and still sharp like a razor. Long life Baba. Looking good, great memory and a great historian.

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    Жыл бұрын

    Ẹ kú ìmọyì Bàbá o

  • @williampowers2109
    @williampowers2109 Жыл бұрын

    Wow!!! This is quite interesting 🤔 👍 😳 👌 👀 🙂

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    Жыл бұрын

    Thanks for appreciating it

  • @yinkadoyinbo2695
    @yinkadoyinbo2695 Жыл бұрын

    Baba got a sharp memory and highly intelligent old man. Ke pe o Baba

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    Жыл бұрын

    Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o

  • @olatubosunfisayoojo7573

    @olatubosunfisayoojo7573

    Жыл бұрын

    Yes, those grandpas memory is 100%. My grandpa too was a historian. He will tell you everything about Oyo as this grandpa rightly said

  • @olatunjiolaleyetaofeek4322
    @olatunjiolaleyetaofeek4322 Жыл бұрын

    I love this program ❤

  • @isaacoladapo169
    @isaacoladapo169 Жыл бұрын

    Very intelligent Papa.

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    Жыл бұрын

    Ẹ ṣeun o

  • @tominiyiakinyele4426
    @tominiyiakinyele4426 Жыл бұрын

    Thank you for this video. You make me remember my childhood. I leaved 5 houses away from Baba Ogunmola when I was young. Long life Baba

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    Жыл бұрын

    Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ kú àìgbàgbé o. Ẹ ṣeun púpọ̀

  • @olugtesile9569
    @olugtesile9569 Жыл бұрын

    How i wish to meet baba very nice interview 👍

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    Жыл бұрын

    Baba is still agile

  • @golfoscal75
    @golfoscal75 Жыл бұрын

    God bless & preserve you Baba. As your years so shall be your strength. I am so impressed by you sir.

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    Жыл бұрын

    Ẹ ṣeun o

  • @ojogabriel3627
    @ojogabriel362711 ай бұрын

    Christian ni yin sir! Kin lo de ti won fi ma nso wipe christian o le joba Alaafin OYO?

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    11 ай бұрын

    Nítorí pé Kristẹni kìí sáábà fi ara mọ́ àwọn àgbéjẹ-gbémì tó rọ̀ mọ́ ipò Alaafin

  • @1004445
    @10044452 жыл бұрын

    It is nice to hear from an old wiseman 👍🏾.

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    2 жыл бұрын

    Ẹ ṣeun, ẹ̀yin náà á dàgbà iyì o

  • @crownxydayo313
    @crownxydayo3132 жыл бұрын

    You are doing well MA

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    2 жыл бұрын

    Ẹ ṣeun púpọ̀ o

  • @horladtoptimtop5625
    @horladtoptimtop56252 жыл бұрын

    Waiting for Archbishop Ladigbolu interview

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    2 жыл бұрын

    Ó ń bọ̀ láìpẹ́ jọjọ

  • @horladtoptimtop5625
    @horladtoptimtop56252 жыл бұрын

    You are doing a great interview

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    2 жыл бұрын

    Ẹ ṣeun púpọ̀ o

  • @marymakinde33
    @marymakinde332 жыл бұрын

    Eku agba , Baba wa tooto, God will continue to uphold and flourish you for us in Jesus mighty name Amen

  • @isedaleabinibiwa2020

    @isedaleabinibiwa2020

    2 жыл бұрын

    Àmí. Ẹ ṣeun púpọ̀ o

  • @titusodunlami7766
    @titusodunlami7766 Жыл бұрын

    Are these 119 candidates all from Agunoye family?

  • @afolakemifalana7580

    @afolakemifalana7580

    Жыл бұрын

    God blessed you sir.

Келесі