(Ọmọọdọ Agba) ABI EPE N JA IRAN YORUBA LOOOTỌ NI

Ойын-сауық

We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Пікірлер: 34

  • @alimatthew4931
    @alimatthew4931Ай бұрын

    Ibara eni je, ilara, atenuje, emi oni gba, iwo oni gba, aini ife, Yoruba ko ronu rara sugbon karimi, ayeye ati faari ni ti Yoruba, awon agbakagba po ninu orile ede wa😢😮😢

  • @pauloladimeji2514
    @pauloladimeji2514Ай бұрын

    Yes, beeni oo, odabi epe nja Yoruba. Ewo bi awon omo Ibo se towo bo opolo awon Yoruba leko lati gbogun ti Tinubu leko, koda koto di wipe Tinubu gbe apoti lati dije fun ipo Aare bayi. Otun gbe apoti tan awon Yoruba tun npariwo pelu awon ibo ati omode lati gbogun ti Tinubu wipe o yan, Musulumi ni igbakeji re, se kosi Cristian laye mo ni? Kolorun je ki awon Iran Yoruba gbon ni o. Wahala ti awon omode Yoruba nda sile kiise kekere rara. O ga ju.

  • @lukmonolamilekan8616
    @lukmonolamilekan8616Ай бұрын

    Òmò odo agba have said it all

  • @omoyelesamson2150
    @omoyelesamson2150Ай бұрын

    All you said it's a bitter truth; but if Bola Tinubu has it in mind to do any projects in Yoruba land, he doesn't need to wait for request or approval of any groups before he embarks on such projects.

  • @Oodua-ii

    @Oodua-ii

    Ай бұрын

    Here, hear!!

  • @RazeedAyinki
    @RazeedAyinkiАй бұрын

    Olorun osaun wa Amin oooooooooo

  • @sakenatafolabi8666
    @sakenatafolabi8666Ай бұрын

    ODODO ORO PANUBELE OPOLO YIN ONI JOBA ALAROYE AMIN KUNFAYAKUN 🙏🙏🙏

  • @mustaphaodeshina5111
    @mustaphaodeshina5111Ай бұрын

    Good job 👍 Omo odo agba I.e Faith Adebola

  • @lanrea9373
    @lanrea9373Ай бұрын

    Olori buruku ni awon Asiwaju ni ati ni. Afenifebi ole ako tile ta niwon alatenuje niwon.

  • @florencebeauty7322
    @florencebeauty7322Ай бұрын

    Epe o jawa o ,esin lo nja wa lepe.

  • @adeyemoademolajammy2002
    @adeyemoademolajammy2002Ай бұрын

    Awon oloselu lo nba ile yoruba je, kii se eni keni, ona ofun arawon ni awon oloselu nja fun.

  • @kemoblunsky3794
    @kemoblunsky3794Ай бұрын

    Hmmm, oro na so si ni lenu, otun bu iyo si.

  • @sanitempleprayer472
    @sanitempleprayer472Ай бұрын

    Àwon ota ti fi yaasin ati orisirisi adua da aarin Omo yoruba ru afi ki oluwa kogbawa o Amin

  • @abetoba2331
    @abetoba2331Ай бұрын

    Alaroye e ku ise, awa omo YORUBA TI bere ohun ti afe , Sugbon BOLA ko, osebi ohunkogbo YORUBA NATION NI GBOGBO OMO YORUBA PATAPATA FEEE

  • @mrscpower6200
    @mrscpower6200Ай бұрын

    Beni o. Enu Yoruba ko ko rara

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo6681Ай бұрын

    ALAROYE ORO NLA LE SO YI O AYAFI KI OLORUN GBASAKOSO OHUN GBOGBO ELEYI TOJU SU WA NILE YORUBA KI OLORUN BA WA DA SI ORO NA A SESE LOGO OLORUN AMIN ATI

  • @user-qg5ur2sf7p
    @user-qg5ur2sf7pАй бұрын

    Ooto oro ponbele ,Olorun yio bawa se ,Oduduwa yio gbe wa o.

  • @olajideoluwayomi6529
    @olajideoluwayomi6529Ай бұрын

    Ọlọ́run jọ̀wọ́ gba Yorùbá lọ́wọ́ ègún aimọ àti èpè iran

  • @Oodua-ii
    @Oodua-iiАй бұрын

    Yoruba Nation an exit out of fulanigeria is the solution. Tinubu can not save us he is here for himself.

  • @oduatide6849
    @oduatide6849Ай бұрын

    EPE N JA AWON POLITICIANS YORUBA NIKAN, EPE YEN LOMA PAA GBOGBO WON KU. EPE KO JA OMO YORUBA RARA,ABI EPE N JA OMOODO AGBA NONI?

  • @bodew4836

    @bodew4836

    Ай бұрын

    😂😂😂

  • @9ty214
    @9ty214Ай бұрын

    Tinubu divided afenifere in to different versions because of his political interests oniburuku ni gbogbo won

  • @Oodua-ii
    @Oodua-iiАй бұрын

    Disagree or agree with omo odo agba show love, please give 👍for rich opinion editorial.

  • @adekunlefodilullahmfa7700
    @adekunlefodilullahmfa7700Ай бұрын

    Otoro ni Aloroye nso haaa se epe nja iran Yoruba ni Afi kii olohun saanu wa ooo Olori buruku gba ni awon tii wan pe ara wan ni afenifere yii Bcs ti kobaribe ni kii lode tii gbogbo wan o se fii enuko pelu Baba prof banji Akintoye kii agba Yoruba nation Afi kii olohun saanu wa kii o ran iran Yoruba lowo kii o bawa saanu fun baba Akintoye kii wan ba wa gba Yoruba nation kiakia ooo

  • @oyedokunaminat2871
    @oyedokunaminat2871Ай бұрын

    Hmmmmm Blood of Jesus

  • @osowoolalekan777
    @osowoolalekan777Ай бұрын

    Kantakanta ti yin nan po asoro so boto ni alaroye, elo ni suru.

  • @mrscpower6200
    @mrscpower6200Ай бұрын

    Beni o, it is true o. Epe nja Yoruba ni o bi mo se lero. Afenifere ko ni won they are Afenifebi ni gbogbo won

  • @alabaadejumo535
    @alabaadejumo535Ай бұрын

    Ko si ore kan ti Tinubu ma mu ba omo yoruba, nitoripe ile yoruba ti jade kuro ni inun Nigeria.. ti o ba fe so otito oro fun omo yoruba, SO FUN WON PE KI WON BOSITA KI WON GBA ETO WON.. ODUN MESAN WON SHI BORDER KI OUN WOLE SI ILE YORUBA..

  • @mustaphaodeshina5111
    @mustaphaodeshina5111Ай бұрын

    Obasanjo has nothing to say!! The fighting between two Kings has nothing to do with Obasanjo incompetence!!! Obasanjo is the most useless President Nigeria has ever had. He is has ugly as his character when it comes to Yoruba people. The guy will never die well

  • @oluwoleebenezert-qq2be
    @oluwoleebenezert-qq2beАй бұрын

    Ko si ooto eyo kan bo ti wu ko kere mo ninu analysis yin rara. Tribalism lasan le n se agbateru re. Se agbaagba Yoruba ni constitution orile ede? Se won de owo Bola Tinubu lati mu ki NEPA se daadaa? Industry melo lo ti da sile? Refineries melo ni Bola Tinubu ti da sile? Alaroye e pelu awon to n da Nigeria ru pelu iroyin buruku ti e n ka jade yi. Se bi America se di nla ree? Ani ki Nigeria decentralize bi America to ni 50 independent states not depending on the centre, e n ka iroyin ti ko mu laakaye jade. Alaroye, ko daa o.

Келесі