(Ọmọ-ọdọ Agba) AANU BỌLA ṢE MI, TEMI ṢE ỌLỌRUN

Ойын-сауық

We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Пікірлер: 27

  • @Oodua-ii
    @Oodua-ii4 ай бұрын

    If you wishes for good content please love and like this video.

  • @joysobowale8584
    @joysobowale85844 ай бұрын

    Orile ede Yoruba nikan soso lona abayo, ipinya tide tan. Yoruba Nation Otisese pelu ase Eledumare ami.

  • @mariamasie9329
    @mariamasie93294 ай бұрын

    Bola Tinubu Ole, akotileta ,arungun, Olojukokoro,obayeje

  • @tyade7969
    @tyade79694 ай бұрын

    Alaroye Olorun a Duro tiyin o. Omo odo agba ojulowo Omo yoruba ni yin … e ba wa ma ran Bola leti every month Ki Awon Fulani to ti ijoba re subu . Thank you Alaroye eni a wi fun oba je ko gbo …. E ba wa fi ranse si Awon Abesinkawo Bola like Baba Akande , baba Osoba , baba Olusi , baba Okurinmu .

  • @ShokotoOlomide-us4ej
    @ShokotoOlomide-us4ej4 ай бұрын

    A ti so fun won pe ko si solution fun oro nigeria

  • @Solomonity
    @Solomonity4 ай бұрын

    Very true talk. Better for each (3) tribe to be separated. Every one knows that Nigeria cannot be better, why do we keeps deceiving each others? Bad people, bad country.

  • @user-op5mx3jk7t
    @user-op5mx3jk7t4 ай бұрын

    BOLA HAMMED TINUBU gangan ni Number One tio tawaa fun FULANI , TINUBU lo mu BUHARI waa ooo , yifiowo Sowopo pelu BABANGIDA nioo Ki BOLA HAMMED TINUBU lese olori as president , TINUBU BOLA HAMMED lo bati gbogbo YORUBA jee ooo , Afi kio tunse kio to kuro nibee ooo .OJUKOKORO OLEEE ati Yimotii Araa Eni nikan 😢

  • @richardearl2731

    @richardearl2731

    4 ай бұрын

    True talk. He’s still selling Yoruba

  • @GbemisolaOgungbemi67
    @GbemisolaOgungbemi674 ай бұрын

    Tínubu apani mayo da, ní bàbà yẹ ṣùgbọ́n ìbínú Ọlọ́run ti dé láti ṣe idajọ gbígbóná le lori gege bí èrò ọkàn rẹ sì ilẹ̀ Yorùbá, adabi to bá je ki ṣe ilé Yorùbá ni wọn rí OLUBI rẹ sì, mo nbo wá Ọlọ́run kò yà lógún ọdún ọ̀rọ̀ Ọlọ́run kò ní lọ lai má ṣe òòò.

  • @Oodua-ii
    @Oodua-ii4 ай бұрын

    Omo odo agba, you always come with a wealth of knowledge, and I especially like your first map, which depicts the south in all its glory. Please try using the western region map; it is more accurate than these military maps.What is the Yoruba indigenous homeland without Kwara and Edo to Warri?

  • @olufemiajibola5209
    @olufemiajibola52094 ай бұрын

    Oluwa yio gba Yoruba kuro Loko Eru Awon Fulani

  • @jamiuibrahim715
    @jamiuibrahim7154 ай бұрын

    Ododo Oro 👌

  • @AyotundeOjuade
    @AyotundeOjuade4 ай бұрын

    Separation is the best solution, Nigeria will never be a great country, Tinubu can only try but next president will also complaining.

  • @oladejimu-oz4kk
    @oladejimu-oz4kk4 ай бұрын

    Monlu jije ni fun yoruba

  • @TAYETAIWO4499
    @TAYETAIWO44994 ай бұрын

    OOTO OORO KONI KASO OHUN

  • @kolaziloris870
    @kolaziloris8704 ай бұрын

    Good talk ! My contribution is this Tinubu is among those that sold Yorubas to the Fulani but let me tell you a adage that says omo ina la ran sina Tinubu cause most things happen and he's only one that can resolve it before is late and as it is now 9ja should go back to regional government or separate the government, Fulani are minority in 9ja, they stylishly suppress the original hausas, the Igbo and they're about to overpowered Yoruba and take over all 9ja. We don't have much time to waste either regional or divide 9ja.

  • @samuelosonuga3490

    @samuelosonuga3490

    4 ай бұрын

    200 percent correct 😊

  • @user-mi5lw8sj9v
    @user-mi5lw8sj9v4 ай бұрын

    O Pe Kin N'to Gbon Ara Ogbon Ni.. Ni Igbati Ododo Oro Ti Jade Bayi.. Bi Ise Ko Peni, Enikan Ki Ipe Ise.. Won So Fun Tinubu, Ohun Lo Mo Ohun To Ri... 😢😅... SUNGBON Sibesibe Atunse Si Wa Lowo Tinubu...

  • @omoshewayinka2581
    @omoshewayinka25814 ай бұрын

    Aare ni won gbe wa le Fulani lowo nitori owo sugbon enu ę ni awon na wa bayi . Ki Olorun bawa dawo le orire ede Nigeria 🇳🇬

  • @lucyonikoyi6183
    @lucyonikoyi61834 ай бұрын

    Ki Tinubu ki Òo Pinwaniya Ni koSi ani ani Kan Ni ibe e

  • @abetoba2331
    @abetoba23314 ай бұрын

    Bope titi OGUN ODUN UNBOWAKU OLA , OJOKAN MAJE OJOKAN ,TINUBU MAKURO LORI OYEARE ,SUGBON HOOO ORUKO TINUBU KONI PARE NINU IWE ITAN OMO YORUBA, AWON ARANMO DOMOE MABANINU IWE ITAN, BOLA LOBA YORUBA NATION JEE MONWON LOWO

  • @user-op5mx3jk7t
    @user-op5mx3jk7t4 ай бұрын

    Kodaa nigbogbo Airport HAUSA ,FULANI nioo Haaa

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp4 ай бұрын

    HNNNNNNNNNN

  • @kissprecious
    @kissprecious4 ай бұрын

    Tinubu tie gbiyanju die....o n gba awon Yoruba lati igba ti o ti wo le.

  • @olawaleajayi5482
    @olawaleajayi54824 ай бұрын

    Listening to the first 2mins shows poor research and understanding of Nigerian history.

  • @user-ox1qy6nt1p
    @user-ox1qy6nt1p4 ай бұрын

    Seri.awon.olomowe.wayi.niwon.omountiwonse.ati.awon.ojelu.yigani.wahala.wa.ati.awon.Oba.wayina.ogbeyin.edakun.Alaroye.bawo.lawase.koleye.won

Келесі