KI LO N Ṣ'AWỌN ỌMỌ OJU-O-RỌLA-RI TO WA L'EKOO YII GAN -AN NA

Ойын-сауық

We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Пікірлер: 21

  • @user-vx5pg3re3j
    @user-vx5pg3re3j27 күн бұрын

    Omo Eko gidi kin so isokuso oro jade lenu.

  • @omotayosuccess9576
    @omotayosuccess957627 күн бұрын

    Mama yoruba I salut you ma.

  • @giveway...6838
    @giveway...683827 күн бұрын

    Omo Aale niwon, ni gba tose pe won le sise ole, 419, yahoo... Eranko ni won e fi won sile

  • @kehindebellosikirubello989
    @kehindebellosikirubello98926 күн бұрын

    I love you good woman more wisdom and blessings

  • @tyade7969
    @tyade796926 күн бұрын

    Awon Omo aale ile yoruba ti wa ndagba bayi o . Won ti gbagbe pe Awolowo lo fi owo western region build Apapa Port wharf ati Tin can port … Ilupeju industrial estate nko? Ikeja industrial estate nko ? Oregun industrial, Ogba industrial nko ? Se Owo isale eko ni won fi ko ? Awon Oponu to nyo eko kuro ninu yoruba ewo ninu won ni ojulowo Omo Eko? Se Akinolu ni ? Se Sanwo olu ni ? Se Ambode ni ? Se Tinubu ni ? Awon Omo oju o rola ri to nso omo re ni Olaniyonu .

  • @Babatope-up4iu
    @Babatope-up4iu27 күн бұрын

    Nigbati Omi ba gbona igbin paapaa a daa mo. E Fi awon Omo ale atokowabaleje won sile. Onikaluku a mo Omo ibi to ba nse nigba to ba ya

  • @bolajisarafadeen3279
    @bolajisarafadeen327927 күн бұрын

    Eseun iyawa alaroye Gbogbo awon toun.soisokuso Omo ale niwon awon ni won pe ni oledarun efiwon sile won fepaun

  • @jamiuomogoriola8300
    @jamiuomogoriola830026 күн бұрын

    Mamami alaroye mogbafunyin gidigidi

  • @alabaadejumo535
    @alabaadejumo53527 күн бұрын

    Mama Alaroye, bawo ni mo shee fe so fun yin wipe, ile yoruba olominira D.R.Y. ti kuro patapata ni Nigeria, gbogbo atotonu ti won nso ko ni kini kan shee pelu orile Ede Yoruba. Tinubu gan mo wipe orile ede yoruba ki nshee ara Nigeria mo, lati 12th April, 2024.

  • @reusamanda9758

    @reusamanda9758

    26 күн бұрын

    What’s the name of your DRY currency

  • @user-ob1fo5yt2r
    @user-ob1fo5yt2r25 күн бұрын

    Mamma alaroye olotito oro

  • @BisiriyuoOwolabi-mc4ox
    @BisiriyuoOwolabi-mc4ox24 күн бұрын

    Wonti fun igbira loti mu, kilafereti lenu awon Olosi eniyan.

  • @user-kl6eq5ej9q
    @user-kl6eq5ej9q27 күн бұрын

    Ki won je ki won da duro, omin to won gbojule iru omin be wa ni ipinle eko Leyin ti south south ba nin sea port ti won Nan nin ile won, ti Yoruba Nan ko tiwon nan lo SI ipinle ondo won yio man nkan ti won karabo

  • @tundeolagbami4928
    @tundeolagbami492827 күн бұрын

    Oledarun omo apakose oponu

  • @ezekielfolorunso6741
    @ezekielfolorunso674127 күн бұрын

    Thanks very much for your fantastic wisdom and knowledge. Mama Alaroye.

  • @wosilatamosu9017
    @wosilatamosu901727 күн бұрын

    ORO GIDI niyen Awon Hausas olé Efon niwon Omo Eko gidi kogbodo sope Eko kinse île Yoruba

  • @fatalkehinderaheemat1513
    @fatalkehinderaheemat151326 күн бұрын

    Aye lo se won abimo na ni yo gbe yin oro awon ti won eko ki se ara ile Yoruba o da be ki ah pada si elekun je jekun ooo ki o ni ka luku mo babu ara re

  • @braitkhamadetokun8578
    @braitkhamadetokun857825 күн бұрын

    That issue of lagos not yoruba need to be addressed olorun

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo668127 күн бұрын

    E SEUN IYA ALAROYE E BA MI SALAYE FUN WON KO LO YE WON DADA OPOLO OPO NINU AWON TO TI OHUN WA TI WON NPERAWON NI OMO EKO MI OPOLO WON SUN SEHIN WON O LE RONU BOTITO ATI BO TI YE A SESE FUN WA LAGBARA OLORUN

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq40126 күн бұрын

    Awon dindinrin wo niyen Won sife ba ojo ola Ipinle Eko je

Келесі