Itan Lehin Iku Aare Afonja 12

Apá kejila ni bí ogun Ibadan ṣe lọ ranro ni Erunmu àti bí Aláàfin Oluewu ṣe jẹ
Laji Abbas Whatsapp +2348023687432

Пікірлер: 8

  • @hamzatjamiu4926
    @hamzatjamiu49263 жыл бұрын

    May Almighty Allah bless you and your generation

  • @wosilatamosu9017
    @wosilatamosu90174 жыл бұрын

    Awon Baba wa won damun île aye awa omo loni Abosi wa kunlo HUUUUM Olorun a kowayo Yoruba Ejeki konupo kaserawa lokan ki Yoruba le roju rayé. Laji Abbas Eku Ise Takuntaun ODUA Agbewa ASE

  • @hamzatjamiu4926
    @hamzatjamiu49263 жыл бұрын

    You are the best

  • @thickbarbieskitchen1159
    @thickbarbieskitchen11594 жыл бұрын

    Hmmmmm ki awon oba ati gomina wa ma gbo eto yi ooo

  • @tosinogunniran3386
    @tosinogunniran33864 жыл бұрын

    Ese pupo oluko agba, mo se iranti wipe mo bere ni owo yin ni pa oun to gbeyin Ade isembaye olowu.

  • @abdulmumeenwaliyyullahi8569
    @abdulmumeenwaliyyullahi85694 жыл бұрын

    Eku use sir

  • @oluyemisiadenmosun9877
    @oluyemisiadenmosun98774 жыл бұрын

    Oluko agba! E ku ise takuntakun ati ti akoni. Olorun yoo maa ti yin leyin. AAMIN LORUKO JESU KRISTI OLUWA WA.

  • @thickbarbieskitchen1159
    @thickbarbieskitchen11594 жыл бұрын

    Eku ise ooooo