IMAMU EGBA ATI IMAMU OGBOMOSO E SUN MOBI !!!

Пікірлер: 71

  • @akeukerekeolatunji9702
    @akeukerekeolatunji970212 күн бұрын

    Naam. I saw the video. It was a big shame on the Alakatakiti. May Allah continue to protect and uplift Islam.

  • @user-ch3dj6fn5f
    @user-ch3dj6fn5f12 күн бұрын

    Imamu ko fi tinutinu be Oba o. Kayelerimi pe mo be Oba lasan ni. Imamu gbon sasa!. Baba Imamu Egba ti so pe ija esin ni awon nja. Mo wo lori Benbeyeke tv. Ki won sa ma ba ile yoruba je fun wa. Musulumi latijo ko ri bayi, omo iya ni gbogbo wa

  • @adetounolorundami5257

    @adetounolorundami5257

    12 күн бұрын

    awon omo ale buruku yi dapo mo won

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami525712 күн бұрын

    may God continue to give you more wisdom and knowledge .

  • @OgundejiHakeem
    @OgundejiHakeem12 күн бұрын

    Good of you my brother. Otito oro gan loso . Emi naa wo imam egba so jade lenu awon oro tiko ye ki agbalagba so ni imam egba so

  • @mosesayoadeleke6806
    @mosesayoadeleke680611 күн бұрын

    Omo ale eniyan po ni ilu ogbomoso imman yunusa ki se ise olorun lo wa se o kan wa lati da alaafia ogbomoso ru ni Allah ko ni fun gbogbo won se amii

  • @Souleman-nv8zi
    @Souleman-nv8zi11 күн бұрын

    Good bless you sir

  • @kayodegbadegesin2820
    @kayodegbadegesin282012 күн бұрын

    God bless you my brother, dajudaju Okan lara awa Omo Oko Ogbomoso ni e je. I love you sir. The truth has been spoken.

  • @mustaphaodeshina5111
    @mustaphaodeshina511112 күн бұрын

    Good take 👍👍👍

  • @JideCrown-dk7tt
    @JideCrown-dk7tt12 күн бұрын

    I like this man. He's saying the bitter truth. God bless you, God bless Oghomosho

  • @olugbengaoyewusi9835
    @olugbengaoyewusi983512 күн бұрын

    That imam of Ogbomosho is deliberately blackmailing the Kabiyesi because he knows something is wrong with his appointment as imam. He is now using outsiders to recruit supports for himself.

  • @basheeraliyu9827
    @basheeraliyu982712 күн бұрын

    Kudos to you mashallah

  • @SirG_world
    @SirG_world12 күн бұрын

    Ala ni yo go fi oko ole han people is getting to know the truth little by little, Weldon brother

  • @bumishaw7094
    @bumishaw709412 күн бұрын

    You are very intelligent my Bro....👍

  • @SirG_world
    @SirG_world12 күн бұрын

    My brother you are Weldon,I watched the interview from the beginning I got to know that the presenter is working on contract basic

  • @fataihonest
    @fataihonest12 күн бұрын

    Ebe abosi ni onbe oba ,

  • @abbeymore7657
    @abbeymore765712 күн бұрын

    God blessed you my brother ❤continue saying the truth

  • @SerahGibson
    @SerahGibson12 күн бұрын

    Arakunrin mi, Oluwa yio jeki o dara fun o.Sugbon efi sile, baba yen kise baba ti enia fi toro baba.Younis iba wa lori social media.Ani mo so fun o Arakunrin wa.ejeki o lo, BI nwon ba bi omokunrin yen dara, ki o ma sofun. Kosi eniti o je omo Ogbomosho,

  • @fataihonest
    @fataihonest12 күн бұрын

    Imam egba ati mufutty ota musulumi niwon oye ki woo yo imam Yan ni , nitori kosi iwa musulumi lowo won rara

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami525712 күн бұрын

    omo oko musulumi , olorun oba aduro tiyin

  • @user-nj3qx4xh2d
    @user-nj3qx4xh2d12 күн бұрын

    🤣🤣🤣🤣🤣 kudo's to my Alfa

  • @ditty6828
    @ditty682812 күн бұрын

    His the 1st PhD holder in Ogbomoso. 😂😂😂😂😂 Ole jatijati onijibiti.

  • @ditty6828
    @ditty682812 күн бұрын

    O da bo se wi sita o. Abosi ni ipile isilamu so oro awon baba baba yen o je titun rara.

  • @mosesayoadeleke6806
    @mosesayoadeleke680611 күн бұрын

    Awon ti pe ara ni eniyan olorun sugbon eniyan esu ni won ki Allah gba wa lowo awon omo ale ti won fe da ilu ogbomoso ru awon nu olorun nu

  • @rasaqjelili
    @rasaqjelili12 күн бұрын

    Iman tio gbajumo ju lo ni ile Yoruba,imam ogbomoso,alhamdulillahi

  • @gasteeroy8518
    @gasteeroy851812 күн бұрын

    It's clear that imam yinusa is omoale

  • @user-th4en9yy4m
    @user-th4en9yy4m12 күн бұрын

    Tenants and landlord

  • @nojeemalebiosu9885
    @nojeemalebiosu988512 күн бұрын

    awon to ba oba yen contest yen lo sponsored imam toliat ogbomoso ti mu rong person lati mu iru eleyi fun imam yin emawo atun botan imam yi eyin omo oko ogbomoso len soro yi

  • @ajanirufus5929
    @ajanirufus592912 күн бұрын

    That man, Yinusa is not from Ogbomoso, he can't be from Ogbomoso and sit down listening to someone insulting your king. He is not for peace, his action shows that, how can you and your followers post a video of someone insulting your king. He is a fake believer in Islam, he did not believe what he preaches to the people.

  • @teejay9674
    @teejay967412 күн бұрын

    Ologun ni awon Egba, the imam is elegun

  • @fataihonest
    @fataihonest12 күн бұрын

    ❤❤❤❤

  • @fataihonest
    @fataihonest12 күн бұрын

    Woni eko rara ,oba kiise egbe babanla baba won

  • @solabolaji5364
    @solabolaji536412 күн бұрын

    Ti e o ba lé ọmọ ale sita, inu ile ko le toro.

  • @user-rq8fq9mz9e
    @user-rq8fq9mz9e11 күн бұрын

    Oye ki won arrest baba ye,Tori nleri ogun SI oba, agba ti o tole

  • @ditty6828
    @ditty682812 күн бұрын

    The guy is a blogger imam. His not different from saidi shittu and co.

  • @fataihonest
    @fataihonest12 күн бұрын

    Ara yio san pa gbogbo eni ti kofe oba ganbi ,woo nini isinmi

  • @user-rq8fq9mz9e
    @user-rq8fq9mz9e11 күн бұрын

    Awon agba kantankantan okan mi baje nigbati Mori video baba ye

  • @SerahGibson
    @SerahGibson12 күн бұрын

    Yinusa ma pada losi ilu nwon.Igbati mo ri gbogbo, ki se Imam Ogbomosho. Yio pada kuro ni Ogbomosho ni.Yio pada losi ibiti nwon bati bi.Olorun mope Yinusa na ma pada losi ibiti nwon ba ti bi.Gbogbo ori social, on na mo pe yio pada losi ilu ti nwon ba ti bi .Emi komo ibiti nwon ti ri omo radarada be.Yinusa kise omo Ogbomosho. Igbati o jewipe OLORIBURUKU omo poju awon abipabe. Eniti ngbija. Arakunrin iwo fi nwon sile, akoni salairi omo radarada iru re. Kise omo Ogbomosho. Enyin efi sile, Gbogbo omo ti o ba ma sonu koni gbo fere olode, Yinusa kise omo Ogbomosho. Efi awon omoale sile. Baba mi eru Olorun, fi nwon sile. Olorun yio fi ire fun o,Arakunrin mi ye parowa fun nwon.Kolesese Yinus ni nwon npe, omo Fulani ni.Se ti ija esin ba sele ni Ogbomosho, Se Ogbomosho wa je eniti nja gbogbo ija ti obati sele ni Ogbomosho, nwon o mope okansoso ni gbogbo ni Ogbomosho. Ao tile wa Yunis ni Ogbomosho.

  • @ditty6828
    @ditty682812 күн бұрын

    Propaganda ni oyato imposter imam yin nse. Those people knows the truth but because of isilamu is full hypocrisy.

  • @olawaleodedina8557
    @olawaleodedina855712 күн бұрын

    Iwo ti soroyi olorun yio dara fun e . Imanmu oloribuku ni. Olorun yiotioleyin

  • @yemmie4280
    @yemmie428012 күн бұрын

    Alabosi ni Imam Ogbomoso. It is evidential that he is not from Ogbomoso. Imam Ogbomoso kii se omo bibi Ogbomoso. An indigenous son of Ogbomoso would not allow the throne of his town be denigrated.

  • @arinolamayaki7487
    @arinolamayaki748712 күн бұрын

    Emi o ki nse Omo Ogbomoso, Omo Oba Ijebu Ode ni mi, asise nla ti ba Imam Toliat, iyen fi daju pe Toliat ki ise Omo Ogbomoso gidi Taofiki yen is a criminal and he will lead the government to where and the person who told him all the nonsense he said Se ko si awon Baba Imam gidi ni Ogbomoso ni? Eni ti Olorun ba ti fi sipo, ko seni to le yoo lailai Toliat should be removed with immediate effect! He is not fit to lead the Muslims in Ogbomoso. Omo ale ko le se ko ma se ise Omo ale!

  • @OladepoNurudeen
    @OladepoNurudeen12 күн бұрын

    Alfa e e gbenu lowo , eyin Ara alfa oni inkan osu tanso naa re

  • @KarunwiAdeolu-ne5ce
    @KarunwiAdeolu-ne5ce12 күн бұрын

    Imamu egba o ti were ni gbo iko ti lmamu egba ti ko le se Abeokuta

  • @deboodepe8062
    @deboodepe806212 күн бұрын

    Oye ka kiyesara o! Awon t'opa Oba Layode, Soun ojosi, awon Musulumi na l'aba nidi re. E n tun ba bo bayi o. Se oruko rere le n so Islam bayi?

  • @kolataiwo2
    @kolataiwo212 күн бұрын

    Your video has no audio

  • @Kabisanra1
    @Kabisanra112 күн бұрын

    Ori e ti daru omo were onijekuje ebi ti fe fo gbogbo yin loju 😂

  • @wasiukehinde-xg9wg

    @wasiukehinde-xg9wg

    12 күн бұрын

    Omo ale ni gbogbo yin.

  • @adeagaabideenModara

    @adeagaabideenModara

    12 күн бұрын

    Were ni e,se eleyi jo elebi loju re,ara yin ko otito oro ni,iwo pelu imam re ti enleri ogun si oba Gandi,ori gbogbo yin ti gbale

  • @abdullahijibrin3282
    @abdullahijibrin328212 күн бұрын

    SE Alfa nii Iwo sa afa onisese eronu Islam Nile yoruba mehe lati odo iru yin kosi elesin miran tinu reledun si bi Islam se ga logbomoso

  • @adeagaabideenModara

    @adeagaabideenModara

    12 күн бұрын

    Nitori esin ajoji, iwo fi owo osi juwe ile baba re ,ogaaaa oo

  • @SirG_world

    @SirG_world

    11 күн бұрын

    @@abdullahijibrin3282 we all need to apply our Sense,look at case with your own brain think if you are from ayilara family,then if you The King and they brought a case like this to what would you do and see your self as imam is this how you will be doing to a king of your own town to the level of you go and report your king to another immam in another town please use your own brain on this matter

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni946312 күн бұрын

    Imam Teliat Yunusa Olushina is an Iporo Ake man from Ogun State, he is NOT Ogbomoso Indigene. Teliat Yunusa should be remove based on the fact that he is not Ogbomoso indigene and for peace to reign

  • @fataihonest
    @fataihonest12 күн бұрын

    Afa jagidi jagan ni awon mufuty ati awon iyoku re

  • @Kabisanra1
    @Kabisanra112 күн бұрын

    Bawo lose ba islam je

  • @user-ov9mc3iu1i
    @user-ov9mc3iu1i12 күн бұрын

    Rubbish talk, you need to go and look for better things to do, bro

  • @ditty6828

    @ditty6828

    12 күн бұрын

    You are jobless that's why you are on his page.

  • @abbeymore7657

    @abbeymore7657

    12 күн бұрын

    You don’t have sense Try and sleep and think mumu

  • @ditty6828

    @ditty6828

    12 күн бұрын

    The guy talking is more sensible than you. You are the one that is jobless person. Why are you on his page.

  • @deboodepe8062

    @deboodepe8062

    12 күн бұрын

    Eo ri bi? Ara won niyen. Ari otito maso. Oluwa yio ja fun Oba Ghandi Afolabi Olaoye Orumogege III. Ara fun yin ni? Ninu ninu wahala ti e gbe ko laiya, ko so ohunkohun. Kabiyesi Oba, Oluwa yio ja fun yin. Amin Oluwa ni Oba orun ati aiye, amu ni ma le ni, yio gbejo yin ro. Amin.

  • @deboodepe8062

    @deboodepe8062

    12 күн бұрын

    Eo ri owo ti Toliat Junus gbe fun Lemomu Egba ni? Owo lo n lo pa baba bi oti lile!! Baba ri bail owo lo n ba so wototo lai wadi oro. Oloun yio da! Allah ya isa.

  • @fataihonest
    @fataihonest12 күн бұрын

    Imam egba ati mufutty ota musulumi niwon oye ki woo yo imam Yan ni , nitori kosi iwa musulumi lowo won rara

  • @osundunoriginal7176
    @osundunoriginal717612 күн бұрын

    Ona jakujaku longba ...olorun yio bió..coming to social media without creat a chance to see the imam & give advise...oloriburuku Nié oooo😢

  • @wasiukehinde-xg9wg

    @wasiukehinde-xg9wg

    12 күн бұрын

    Omo Ale yo ma wuwa omo ale ni. Imam ati awon supporters re omo ale niwon. Nitori ileto ba ntoro omo ale be ni ko ti fi oju han.

  • @adeagaabideenModara

    @adeagaabideenModara

    12 күн бұрын

    ​@@wasiukehinde-xg9wgbeni oo,emada awon were yen lon