Ija Ore Meji, Oriki Ijesa and Oriki Ibeji by Ogundare Foyanmu

Nínú àwo rẹ́kọ́ọ́dù yìí, Foyanmu kéwì lórí àwọn ẹ̀ka wọ̀nyí:
ÌJÀ Ọ̀RẸ́ MÉJÌ
ORÍKÌ ÌJẸ̀ṢÀ
ORÍKÌ ÌBEJÌ
ÌṢÒRO NÀÌJÍRÍÀ
ỌMỌ ỌDẸ NÍ F'Ọ́MỌ ỌDẸ
OLÓYÈ ADÉBÁYỌ̀ ALÁTA - BABALÁJÉ OGBOMOSO
Bí ẹ bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa Ogundare Foyanmu àti àwọn orin Ìjálá tó ti kọ pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọn, ẹ ríi pé ẹ ra ìwé tí 'ṢAYỌ̀ ALÁGBÈ kọ tí a pè ní ÌJÁLÁ OGUNDARE FOYANMU (ÌJÌNLẸ̀ ÈDÈ OHÙN ẸNU YORÙBÁ).
For more information about Ogundare Foyanmu and insight into his Aré Ìjálá Ọdẹ, make sure you buy a book written by 'ṢAYỌ̀ ALÁGBÈ called ÌJÁLÁ OGÚNDÁRE FỌ́YÁNMU (ÌJÌNLẸ̀ ÈDÈ OHÙN ẸNU YORÙBÁ)
AIF MEDIA is where we tune lives with tongue and culture. AIF MEDIA is a medium with passion to unite Yorùbá people to their heritage; promote and preserve godly virtues from Yorùbá culture, tradition and lifestyle; and give poetic admonitions.
Our networks:
YÒRÙBÁDÙNLÉDÈ | ÌTUMỌ̀ | BIBLICOPOETRY
Enjoy our educational videos!
To learn more about us, please visit our website.
FACEBOOK
bit.ly/AIFMEDIA-Facebook
TWITTER
bit.ly/AIFMEDIA-Twitter
INSTAGRAM
bit.ly/AIFMEDIA-Instagram
Watch, subscribe and share with others.
#aifmedia #ijala #foyanmu #ogbomoso #sayoalagbe #ogundarefoyanmu #yorubapoetry #yorubaliterature #yorubaresearch #yorubapoem #ewi #areode #odale #ore

Пікірлер: 8

  • @kunminiyi5063
    @kunminiyi5063 Жыл бұрын

    Nice Yoruba language beauty

  • @aifmedia

    @aifmedia

    Жыл бұрын

    Bẹ́ẹ̀ni. Ẹwà èdè Yorùbá ni ti Ògúndáre Fọ́yánmu. Thanks for joining us. Blessings!

  • @hamzatjamiu4926
    @hamzatjamiu4926 Жыл бұрын

    So beautiful

  • @aifmedia

    @aifmedia

    Жыл бұрын

    Yes... Thanks for joining us. Ẹ ṣeun.

  • @hamzatjamiu4926
    @hamzatjamiu4926 Жыл бұрын

    Fantastic

  • @aifmedia

    @aifmedia

    Жыл бұрын

    Thanks for joining us here. A dúpẹ́ púpọ̀.

  • @adelakinagbonbioka2696
    @adelakinagbonbioka26969 ай бұрын

    Could you please share a link for the book you referenced in the description?

  • @aifmedia

    @aifmedia

    9 ай бұрын

    I am sorry, this book is not on digital stores. It's only available for local orders. The author is 'Ṣayọ̀ Àlàgbé from Ògbómọ̀ṣọ́, Nigeria.