EYI LOHUN TI IMAAMU OGBOMỌṢỌ ṢE FUN ṢỌUN NIGBA T'AWỌN MEJEEJI PADE N'IBADAN

Ойын-сауық

We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

Пікірлер: 29

  • @lukmonolamilekan8616
    @lukmonolamilekan861612 күн бұрын

    I really love the move of this CP god will continue to give you wisdom and knowledge of setling the rift

  • @musaturaki2018
    @musaturaki201812 күн бұрын

    Idile ayilara e sora yin o, Ema jeki idile yin parun nitori ife okan, Awon olofo tin binu ologo, Koda ki Imamu yunus wa lati Ghana, Musulumi ogbomosho faramo, May almighty Allah bless the chief imam of ogbomosho land. #ILUFEMILOYE 1.

  • @AdelzBeauty
    @AdelzBeauty12 күн бұрын

    Kudos to the Oyo State police for such a reconciliatory move.

  • @ditty6828

    @ditty6828

    12 күн бұрын

    After kneeling down begging the oba, he still went to imam egba and the baba was cursing the oba and his generation unborn. You call that a reconciliatory move?.

  • @AdelzBeauty

    @AdelzBeauty

    12 күн бұрын

    @@ditty6828 really? I didn't know that.

  • @aadeoyemosun0359
    @aadeoyemosun035912 күн бұрын

    Kudos to the CP for this effort. He has done the best thing. Soun and Chief imam should forget the past and plan for the progress of ogbom

  • @SodeeqAlade-jf8bf
    @SodeeqAlade-jf8bf12 күн бұрын

    Nigba ti imam ti bebe ki oba ogbomosho je ki opari oo

  • @adegbiteademola497
    @adegbiteademola49712 күн бұрын

    The real issue is with the Ayilara family as explained by Kabiyesi, Imam should humble himself and reconcile with the family. I hope this video gets to Alfulany, everything he said earlier was completely false.

  • @abioyemonisola6871
    @abioyemonisola687111 күн бұрын

    Igbe tintinni leti awo gbegiri,to ba tan loju ko le tan lokan, That is why we should be mindful of what we are saying and doing,Lemomu has forgot that kabiesi has children,wife and family.And more so social media will never forget they will be reminding you time to time.

  • @giveway...6838
    @giveway...683812 күн бұрын

    Mr Olawale Ajao. Eku ise o! Ilese Alaroye koni baje o... Oro awa Omo Ooduwa gba suru pupo, awa rawa laba ti ara wa je! Nitiro ipo ijoko Ola oun ati ipo Agbara pe o fe mo olokiki eniyan.... 🫣👈

  • @SheikhMJamiuAdebiyi-ps9me
    @SheikhMJamiuAdebiyi-ps9me10 күн бұрын

    Olohun Koni da idile enikan kan wa ru.

  • @jamiuomogoriola8300
    @jamiuomogoriola830012 күн бұрын

    Ejo ti pari niwon igbati imam tibe oba ... olodumare seun

  • @ditty6828

    @ditty6828

    12 күн бұрын

    Lehin e lo tun lo ba imam agba ni Abeokuta ti baba imam egba si nse epe fun oba. Se ija ti pari be yen?.

  • @jamiuomogoriola8300

    @jamiuomogoriola8300

    12 күн бұрын

    @@ditty6828 epe etanu kimo ekeregbe toripe awon ko lolohun toda oba

  • @omolewabello3467

    @omolewabello3467

    12 күн бұрын

    E se Ori elepe ni epe yoo pada si

  • @adebayoojomo1252

    @adebayoojomo1252

    12 күн бұрын

    Bawo ni ejo se pari nigba ti ejo ti Imamu gbe lo si kootu si wa nibe? Abi Soun lo gbe ejo lo si Kootu ni?

  • @jamiuomogoriola8300

    @jamiuomogoriola8300

    12 күн бұрын

    @@adebayoojomo1252 niwon iba tio bati oba pe kiwon mabinu. Dandan ni ki ohun na fa Iwe ipejo ya daun loro batan

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele332212 күн бұрын

    Ori e ope rara Immamu se ona tie pada wa Bebe ala koro omo ale sheik

  • @saheediwa556

    @saheediwa556

    12 күн бұрын

    Hum

  • @loantha2996
    @loantha299610 күн бұрын

    Jagidi jagan

  • @SerahGibson
    @SerahGibson9 күн бұрын

    EJOWO GBOGBO AIYE,WAYIO NI IDI ORO YI SE ENITI KISE OMO ILE AYILARA, TIKI SI SE OMO OGBOMOSHO, SE DANDAN NI KI O WA JE IMAMU.NI OGBOMOSHO NI.SE GBOGBO.NYIN MOPE ESE KISE LASAN.O YEKI GBOGBO ENIA MO DAJUPE, EMASE FUN ALALE ILE TABI KINFI PE PE EMASE FI ENITI KOBA JE OMO ILU ,TOFESE RIN WA,TI KISEPE ORI LO FI RIN .IWO TO KOROJU EWURO LO NI ERANTI PE ENYIN AGBALAGBA TI EBA FE KI IGBEHIN NYIN O DARA,KODA TI OFI MO EMI TI MO NSORO YI.SE KOYEKI ARA O FU NYIN PE ESE KI NSE LASAN, TORIPE ALALE KONI GBA FUN NYIN.NI ORO YI NSE NJA RANINRANIN NLE.SEBI ORO YI TI SELE LATI IGBATI KABIYESI TI O WAJA TI WA LORI OYE NI.KINIDE TI EO JEKI IMAM YI LOSI ILU TO TI WA,LATI YANJU ORO YI FUN.THEN KI NWON YANJU ONCE AND FOR ALL. EMA FUN ILE OGBOMOSHO NI IWO TI OKORO JU ORONRO LO.EMI FI EYI RO NYIN NI,MOSI TUN FI KILOFUN NYIN PE OGUN TOLE JA NYIN LOJO IWAJU.NI,KINIDE TI ENYIN AGBALAGBA TI E MA FEHIN SILE,FE SISE EPE TABI ADURA,SE IPA RAJA NI ABI ENIA NFI.IPA TAJA.NI.THIS MY OWN ADVISED TO ALL MUSLIMS IN OGBOMOSHO.KILODE TI ILU MIRAN MAFI SE AYONUSO SILU TI NYIN THIS THING'S IS GETTING OUT OF HANDS.LETS HIM GO.EJEKI OGUN OMI.IS GLEARING THAT HIM HIMSELF DEEP DOWN IS NOT A NATIVE.ELO BORISA POPO.ELO BE LOWE.KI GBOGBO NKAN YI KI O LE LOJU.AMORAN MI FUN OBA NIPE NWON O LE GBE ORO MOSALASI LEHIN RE.ATOHUNRINWA KAN KOLE DASI ORO ILU ONIKALUKU, ODARA BI O SE GBE KABIYESI LO SILE EJO.IBITI NWON BATI NSE IRU RE.IYALENU NLA GBAA LOJE.BI AWON KAN NI NWON BASI FE DA ILU YEN RU.NI ILE NA LOMA BI NWON LERE TI OSI MASE ETO FUN NWON. OLUWA YIO RAN GBOGBO OLODODO LOWO.GBOGBO ENITI NGBIN OTE OLUWA NA KANNA LOMA SE IDAJO AWON NA

  • @sundayoluwaseun6998
    @sundayoluwaseun699811 күн бұрын

    Awon mugun tiwon ni imamu ni baba obada,sango yiopa bata yiopa jawonjanwon etie

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni946312 күн бұрын

    Ayilara family said Imam is not from their family and this has been proved beyond reasonable doubt by the family. Therefore, they have to remove him

  • @idowuaiyedun2167
    @idowuaiyedun216711 күн бұрын

    Kaabiesiooo. E ku agba. Ki imam wa ona ti yoo fi han fun gbogbo idile Ayilara wipe omo oko loun bibeeko yiyo ni oba yooyo

  • @oluseyeojo3726
    @oluseyeojo372612 күн бұрын

    Abosi po lowo immam why he started pleading if he's right for his actions. Shame and power hustler

  • @adebayoojomo1252

    @adebayoojomo1252

    12 күн бұрын

    Beni, asiwaju ni Imamu je ninu awon alabosi ati elete. Dipo ki o yanju oro ara re pelu awon idile Ayilara, nise lo ngba kootu lo, to si ndogbon huwa abuku ati arifin si Oba. Iru iwakiwa bayi ko ye ki a ma ba ni owo e ni ti o ni iberu Olorun Oba.

  • @user-vx2py3yy6z

    @user-vx2py3yy6z

    12 күн бұрын

    Ayilala family is the problem of Ogbomosho

  • @omolewabello3467

    @omolewabello3467

    12 күн бұрын

    @@oluseyeojo3726 amusat turaki eyin wonyi ni ika tio wa nidi ki won yo toliat nipo nitori Oro buruku Oro kobaku gbe ti nso jade lenu yino ni ogbagbo pe ota alafia ni yin e si nsise to pe ki oriolori gba eto yin bi bee ko e o ni maa pe awon ayilara famili ni olofo ti o nbinu ologo Ogo ti e npolowo da E maa fi laakaye ku nkan ti e ba nso Ija PARI e tun lo nse epe fun oba ni Abeokuta E joko ke ronu eyin eyan buburu Yi le jeki imam mo nkan ti e nde

Келесі