ESI ORO FUN MUFTI IWO ......

Пікірлер: 40

  • @lawaloluwatoyin8703
    @lawaloluwatoyin870329 күн бұрын

    Wow! God bless you Sir..... ❤️❤️❤️🌹❤️❤️❤️ I'm happy that you are not relegated your King. Longlive OBA GHANDI, Longlive Ogbomosho.

  • @ogundareidris9183

    @ogundareidris9183

    29 күн бұрын

    E Mon mufuti Iwo ni, nitori KO le ma da Ile Yoruba ru ni oluwo fi je mufuti Iwo , oun ati oluwo ni mitio ni Ile Yoruba sugbon ti olorun ni yo se, toripe oluwo ati mufuti Iwo won SA pa Mon si Abe esin ni won ki se musulumi, ki olorun ya wa yawon ati awon Omo Ogun won

  • @adeyinkabenjamin4786
    @adeyinkabenjamin478629 күн бұрын

    Mufti fe ki ilu Ogbomosho daru. Olorun yo doju ti.

  • @bottomsuper1877

    @bottomsuper1877

    29 күн бұрын

    Amin

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni946329 күн бұрын

    Good response to senseless Mufti TAHUN Iwo who’s his mouth 👄 had been disconnected from his brain 🧠

  • @user-lo7jy9jf4h
    @user-lo7jy9jf4h25 күн бұрын

    Eyin omo ogbomosho a da fun yin o, ilu ogbomosho ko ni tuka o, ilu ogbomosho ko ni daru o e kare po omo oko ni yin e duro tan, eyin musulumi tooto eyin omo iya dada ninu musulumi e ku aduro ti Oba Gandi alujona ni ti yin ooo. Ajoji to ba wa si ilu ogbomosho lati wa ba ilu je nse ni ke fi eje re se etutu fun awon alale ilu ogbomosho. Awon mufti tahun atohun rinwa wa ba ilu onilu je.

  • @olagokeclaudius3402
    @olagokeclaudius340229 күн бұрын

    omo oko ogbomoso ni yin sir. nice one

  • @aminuphilip1841
    @aminuphilip184129 күн бұрын

    True and sensible Muslims in Ogbomoso, I salute you all. Bi elete ko ba te, ara re kii ro. Ole nfa ole mora, won nfi esin boju fun ise ibi won. Won fe fi tipa-tipa je gaba lori eyin ojulowo musulumi alaafia. Won fe so yin di alakatakiti ati terrorists bii tiwon. Won sebi mumu ni gbogbo musulumi Ogbomoso ati ile yoruba ati Nigeria. Bebi ti seju. Awon eru Alimi afipa gbale fun Fulani. Won fe jise eleje ti won ti gbowo re lati saudi bii Judasi. Enikeni to ba fe gbale Yoruba fun Fulani tabi ti o fe da ogun sile laarin wa, esinkesin ti o ba ti wa, ori ara re ni yoo fi gbee. Oju tie, self-acclaimed, local and unrecognized Mufuti toogi.

  • @kayodegbadegesin2820
    @kayodegbadegesin282026 күн бұрын

    Oloriburuku ni mufty iwo yen, ati wipe gbogbo eyin ti e n ta Ogbomoso sita, eyin alabosi,eyin nu Olorun nu. Emin oba wa Ghandi Afolabi Olaoye Orumogege lll yio gun loruko Jesu.baba wa to Se alaye oro yi, mi agbara Olorun emin yin yio gun fun wa.

  • @ayotuyi1510
    @ayotuyi151029 күн бұрын

    Thank you Baba,you are the best

  • @toyindosunmu795
    @toyindosunmu79528 күн бұрын

    Omo oko Ogbomosho ni baba may your years be long

  • @user-lo7jy9jf4h
    @user-lo7jy9jf4h25 күн бұрын

    Eje mufti iwo ni won ma fi se etutu fun ilu ogbomosho.

  • @adewalejamiu2111
    @adewalejamiu211128 күн бұрын

    This one is too much ooo. May Allah make peace reign in Ogbomoso, and all Yoruba land and in Nigeria as a whole.

  • @abijoakeem3008
    @abijoakeem300828 күн бұрын

    Kaare! Omo Oko Ogbomosho ❤

  • @adekunleabeebuniversal5150
    @adekunleabeebuniversal515029 күн бұрын

    Good we bless you sir true talk sir

  • @AyoolaJimoh
    @AyoolaJimoh27 күн бұрын

    Emoreti isubu awon omo ale ile yooba yi wonole latubotan ire ileyoba kolegbewon

  • @SUCCESS383
    @SUCCESS38329 күн бұрын

    Plan imam ogbomoso ATI mufutau iwo ni wipe won fe ki oba ogbomoso na je ti musulumi nikan ki soun na Le ma se Ori sile biti Rasheed iwo

  • @ditty6828

    @ditty6828

    29 күн бұрын

    The imposter imam wants to use his rascality with his conspirators to frustrate the king.

  • @wassiadeyemitidjani6117
    @wassiadeyemitidjani611727 күн бұрын

    Omolasan ni mufty Iwo yen elenu jawaya omo igbira

  • @sundayoladimeji584
    @sundayoladimeji58429 күн бұрын

    Omo oko kan, ko ni wu iwa omo ale.

  • @Adventure101-jf5bz
    @Adventure101-jf5bz29 күн бұрын

    Good reply 👍

  • @sundayoladimeji584
    @sundayoladimeji58429 күн бұрын

    Ki iru yen ma soro si soun ile Ogbomoso

  • @yemibammeke7668
    @yemibammeke766829 күн бұрын

    Ogbomosho people are intelligent . Well done sir

  • @user-lo7jy9jf4h
    @user-lo7jy9jf4h25 күн бұрын

    Atubotan alabosi koo le da atubotan mufti o le da o ti daju.

  • @anthonyfresh321
    @anthonyfresh32129 күн бұрын

    Well said thanks you sir

  • @waymenloparkozuelipaulobia2682
    @waymenloparkozuelipaulobia268228 күн бұрын

    Bismillah I love this teaching but I don't understand the language. Allah hu Akbar Alhamdulillah

  • @user-lo7jy9jf4h
    @user-lo7jy9jf4h25 күн бұрын

    Ki lo kan mufti tahun pelu oro ilu ogbomosho alaini lakaye oponu ayirada Won le ko nkan lori e nigbati mufti kin se omo saudi ti won ba se were were wonran wonran ni saudi awon ara saudi a be ori e danu.

  • @jameseniolorunda3825
    @jameseniolorunda382529 күн бұрын

    More knowledge sir, this is Yoruba land we are not hausa people, Yoruba nation no going back,

  • @OladepoNurudeen
    @OladepoNurudeen29 күн бұрын

    Yoo to yin eyin Alfa oloplo dundun e gbe adie sidi ke ko agbado sii

  • @user-ju6oe5rd9z
    @user-ju6oe5rd9z28 күн бұрын

    Does it mean that Mufti of Iwo is not a Yoruba man? Because none of the names he displayed bears any Yoruba lineage. Can someone help us verify his root?

  • @ojosamuel1123
    @ojosamuel112329 күн бұрын

    They said mufti tahun iwo is an igede man not yoruba

  • @mamaosun3587

    @mamaosun3587

    29 күн бұрын

    Won ni Igbira ni

  • @famade6526
    @famade652629 күн бұрын

    God bless you Sir. In the olden Days, you are dead when you insult the King. Aroba fin, ni Oba npa. The new Oba Ghandi of Ogbomoso is a peace loving person free of religion. Yorubaland ko ni daru lase Edumare. Awon Omo ale, asiri won yio tu dele

  • @olaoyepeter4677

    @olaoyepeter4677

    29 күн бұрын

    Because of he is christain not alakatakiti family 😂😂

  • @imoleadini
    @imoleadini29 күн бұрын

    Alfa tonsoroyi.olorun.konipa lakae yin.Sewonmope enitoba.sofo lakae.koleje olori.bitiwu omo.walahi.Muftil iwo.oni lakae papa.bitiwu.komo enibawa tiomo.orogbe kale.okanmo.soro jabala komooro.gidi lenu.omoale tikibase peawonomo wogan olaju nibi.tapapode nilu.iwo ewareni.toni lakae.je.muftil.iluiwo ogao.nigba tosepe.ati.imam iwo atoba.irukanna.niwon oponu.muftil osi.olorun.lomo botima.soro muftl.iwo lile.yoba nitori.eleribu.ota.olorunni.muftl wereyio