BABA IYAJI (THE HEAD OF OYO PRINCES)

Èyí jẹ́ iṣẹ́ àkànṣe pàtàkì lórí Ipò Baba Ìyajì tí ó jẹ́ Olórí àwọn Ọmọ-ọba Ọ̀yọ́ pẹ̀lú ojúṣe wọn lásìkò ìpapòdà àti ìyansípò Àláàfin ní ìlú Ọ̀yọ́.
Ẹ má gbàgbé láti darapọ̀ mọ́ wa lójú òpó KZread (Subscribe) yìí láti máa gbádùn àwọn ohun Ìṣẹ̀dálẹ̀ wa gẹ́gẹ́ bí ọmọ Yorùbá àtàtà.

Пікірлер: 28

  • @kudiratoluyemisi6939
    @kudiratoluyemisi6939 Жыл бұрын

    Well done, Olubukola, Alakasu èdè. You are doing great. Keep the fire burning.

  • @igbayilolaoluwarotimijohn5415
    @igbayilolaoluwarotimijohn5415 Жыл бұрын

    Splendid

  • @moradeyoalaba9406
    @moradeyoalaba9406 Жыл бұрын

    E ku eto ilu o

  • @matthewadun7104
    @matthewadun7104 Жыл бұрын

    So Oyo has these attractions for tourists from all over the world. Oyo State Tourist Board should develop and promote them.

  • @williampowers2109
    @williampowers2109 Жыл бұрын

    This is an amazing historical masterpiece that should kept in the archives for prosperity. Wow! I'm stunned into tears watching this great documentary. Great job. Thank you guys. I'm going to share this all over the world 👍 👌 👍

  • @obeyadesoji5301
    @obeyadesoji53012 жыл бұрын

    Mo kí gbogbo Iko Isedale Yorùbá lábẹ́ Aláṣẹ àti Oludari Iyawa Oluwabukolami Adeleke Olùkọ́ Èdè Yorùbá YRB kuu isẹ omoose ó, Làákàyè yín o ni jooba láéláé lágbára Olódùmarè àṣẹ NT'EDUMARE

  • @waheedtijani3153
    @waheedtijani3153 Жыл бұрын

    Thank you for sharing the true history of oyo. Thanks

  • @adekemiadebayo153
    @adekemiadebayo153 Жыл бұрын

    Thank you for this, I am also from Baba Iyaji lineage.

  • @horladtoptimtop5625
    @horladtoptimtop56252 жыл бұрын

    Thanks for the details

  • @adexjohn383
    @adexjohn383 Жыл бұрын

    Nice

  • @jamessmith8049
    @jamessmith8049 Жыл бұрын

    There are other families!!!

  • @jjc5364
    @jjc5364 Жыл бұрын

    Awa ona isokun naa nki yin o

  • @kassimyahaya7707
    @kassimyahaya7707 Жыл бұрын

    But ithought prince Bayo sanda have died since February 2017.