Awọn ololufẹ Dokita Sikiru Ayinde Barrister tún ń bọ ni Naijiria, nítorí Ọmọọba Adebimpe ni o

Ойын-сауық

ọkan lára awọn ololufẹ Dokita Sikiru Ayinde Barrister ni o, ilu òyìnbó ni Ọmọọba Adebimpe n gbé, ojo-ibi ẹ ló fẹ wa ṣe ni Nigeria, bẹẹ láwọn ọmọ ẹgbẹ BARRYFEST ti n mura gidigidi láti wa ba a ṣe é

Пікірлер

    Келесі